42 Ó wá pàṣẹ fún wa láti waasu fún àwọn eniyan, kí á fi yé wọn pé Jesu yìí ni ẹni tí Ọlọrun ti yàn láti jẹ́ onídàájọ́ àwọn tí ó ti kú ati àwọn tí ó wà láàyè.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 10
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 10:42 ni o tọ