43 Òun ni gbogbo àwọn wolii ń jẹ́rìí sí, tí wọ́n sọ pé gbogbo ẹni tí ó bá gbà á gbọ́ yóo ní ìdáríjì ẹ̀ṣẹ̀ ní orúkọ rẹ̀.”
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 10
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 10:43 ni o tọ