Ìṣe Àwọn Aposteli 11:5 BM

5 Ó ní, “Ìlú Jọpa ni mo wà tí mò ń gbadura, ni mo bá rí ìran kan. Nǹkankan tí ó dàbí aṣọ tí ó fẹ̀, tí wọ́n so ní igun mẹrin ń sọ̀kalẹ̀ bọ̀ láti ọ̀run títí ó fi dé ọ̀dọ̀ mi.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 11

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 11:5 ni o tọ