6 Mo tẹjú mọ́ ọn láti wo ohun tí ó wà ninu rẹ̀. Mo bá rí àwọn ẹranko ẹlẹ́sẹ̀ mẹrin ati àwọn ẹranko ìgbẹ́ ati àwọn ẹranko tí ń fi àyà wọ́, ati àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 11
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 11:6 ni o tọ