Ìṣe Àwọn Aposteli 12:11 BM

11 Ojú Peteru wá wálẹ̀. Ó ní, “Mo wá mọ̀ nítòótọ́ pé Oluwa ni ó rán angẹli rẹ̀ láti gbà mí lọ́wọ́ Hẹrọdu, ati láti yọ mí kúrò ninu ohun gbogbo tí àwọn Juu ti ń retí.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 12

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 12:11 ni o tọ