Ìṣe Àwọn Aposteli 12:12 BM

12 Nígbà tí ó rí ohun tí ó ṣẹlẹ̀, ó lọ sí ilé Maria ìyá Johanu tí àdàpè rẹ̀ ń jẹ́ Maku. Ọpọlọpọ eniyan ni ó péjọ sibẹ tí wọn ń gbadura.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 12

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 12:12 ni o tọ