Ìṣe Àwọn Aposteli 13:6 BM

6 Wọ́n la erékùṣù náà kọjá, wọ́n dé Pafọsi. Níbẹ̀ ni wọ́n rí ọkunrin Juu kan, tí ó ń pidán, tí ó fi ń tú àwọn eniyan jẹ. Orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ba-Jesu.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 13

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 13:6 ni o tọ