Ìṣe Àwọn Aposteli 13:7 BM

7 Ọkunrin yìí ń ṣiṣẹ́ lọ́dọ̀ gomina ilẹ̀ náà, tí ń jẹ́ Segiu Paulu. Gomina yìí jẹ́ olóye eniyan. Ó ranṣẹ pe Banaba ati Saulu nítorí ó fẹ́ gbọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọrun.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 13

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 13:7 ni o tọ