Ìṣe Àwọn Aposteli 13:8 BM

8 Ṣugbọn Elimasi, tí ìtumọ̀ orúkọ rẹ̀ jẹ́ onídán, takò wọ́n. Ó ń wá ọ̀nà láti yí ọkàn gomina pada kúrò ninu igbagbọ.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 13

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 13:8 ni o tọ