Ìṣe Àwọn Aposteli 14:8 BM

8 Ọkunrin kan wà ní ìjókòó ní Listira tí ó yarọ. Láti ìgbà tí wọ́n ti bí i ni ó ti yarọ, kò fi ẹsẹ̀ rẹ̀ rìn rí.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 14

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 14:8 ni o tọ