Ìṣe Àwọn Aposteli 14:9 BM

9 Ọkunrin yìí fetí sílẹ̀ bí Paulu ti ń sọ̀rọ̀. Paulu wá tẹjú mọ́ ọn lára, ó rí i pé ó ní igbagbọ pé wọ́n lè mú òun lára dá.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 14

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 14:9 ni o tọ