Ìṣe Àwọn Aposteli 16:18 BM

18 Ó ń ṣe báyìí fún ọjọ́ pupọ. Nígbà tí ara Paulu kò gbà á mọ́, ó yipada, ó sọ fún ẹ̀mí náà pé, “Mo pàṣẹ fún ọ ní orúkọ Jesu, jáde kúrò ninu rẹ̀.” Ni ó bá jáde lẹ́sẹ̀ kan náà.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 16

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 16:18 ni o tọ