Ìṣe Àwọn Aposteli 16:19 BM

19 Nígbà tí àwọn olówó ọdọmọbinrin náà rí i pé ọ̀nà oúnjẹ wọ́n ti dí, wọ́n ki Paulu ati Sila mọ́lẹ̀, wọ́n fà wọ́n lọ sọ́dọ̀ àwọn aláṣẹ ní ọjà.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 16

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 16:19 ni o tọ