Ìṣe Àwọn Aposteli 16:3 BM

3 Òun ni ó wu Paulu láti mú lọ sí ìrìn-àjò rẹ̀, nítorí náà, ó mú un, ó kọ ọ́ nílà nítorí àwọn Juu tí ó wà ní agbègbè ibẹ̀; nítorí gbogbo wọn ni wọ́n mọ̀ pé Giriki ni baba rẹ̀.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 16

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 16:3 ni o tọ