Ìṣe Àwọn Aposteli 16:4 BM

4 Bí wọ́n ti ń lọ láti ìlú dé ìlú, wọ́n ń sọ fún wọn nípa ìpinnu tí àwọn aposteli ati àwọn àgbààgbà ní Jerusalẹmu ṣe, wọ́n sì ń gbà wọ́n níyànjú pé kí wọ́n pa wọ́n mọ́.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 16

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 16:4 ni o tọ