Ìṣe Àwọn Aposteli 17:13 BM

13 Ṣugbọn nígbà tí àwọn Juu ní Tẹsalonika mọ̀ pé Paulu ti tún waasu ọ̀rọ̀ Ọlọrun ní Beria, wọ́n wá sibẹ láti ṣe màdàrú ati láti dá rúkèrúdò sílẹ̀.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 17

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 17:13 ni o tọ