Ìṣe Àwọn Aposteli 17:14 BM

14 Lẹsẹkẹsẹ ni àwọn onigbagbọ bá ṣe ètò fún Paulu láti lọ sí èbúté. Ṣugbọn Sila ati Timoti dúró ní Beria.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 17

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 17:14 ni o tọ