25 bẹ́ẹ̀ ni kò sí ohun tí kò ní, tí a óo sọ pé kí eniyan fún un, nítorí òun fúnra rẹ̀ ni ó ń fún gbogbo eniyan ní ẹ̀mí, èémí ati ohun gbogbo.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 17
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 17:25 ni o tọ