Ìṣe Àwọn Aposteli 17:26 BM

26 Òun ni ó dá gbogbo orílẹ̀-èdè láti inú ẹnìkan ṣoṣo láti máa gbé gbogbo ilẹ̀ ayé. Kí ó tó dá wọn, ó ti ṣe ìpinnu tẹ́lẹ̀ nípa ìgbà tí wọn yóo gbé ní ayé ati ààlà ibi tí wọn yóo máa gbé.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 17

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 17:26 ni o tọ