Ìṣe Àwọn Aposteli 18:17 BM

17 Ni gbogbo wọ́n bá mú Sositene, olórí ilé ìpàdé àwọn Juu, wọ́n ń lù ú níwájú kóòtù. Ṣugbọn Galio kò pé òun rí wọn.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 18

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 18:17 ni o tọ