Ìṣe Àwọn Aposteli 18:18 BM

18 Paulu tún dúró fún ìgbà díẹ̀ sí i. Lẹ́yìn náà ó dágbére fún àwọn onigbagbọ, ó bá wọ ọkọ̀ ojú omi lọ sí Siria; Pirisila ati Akuila bá a lọ. Paulu gé irun rẹ̀ ní ìlú Kẹnkiria nítorí pé ó ti jẹ́ ẹ̀jẹ́ kan.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 18

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 18:18 ni o tọ