6 Àwa náà wá wọkọ̀ ojú omi ní Filipi lẹ́yìn Àjọ̀dún Àìwúkàrà, a bá wọn ní Tiroasi lọ́jọ́ karun-un. Ọjọ́ meje ni a lò níbẹ̀.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 20
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 20:6 ni o tọ