7 Ní alẹ́ ọjọ́ Satide, a péjọ láti jẹun; Paulu wá ń bá àwọn onigbagbọ sọ̀rọ̀. Ó ti wà lọ́kàn rẹ̀ pé lọ́jọ́ keji ni òun óo tún gbéra. Nítorí náà ó sọ̀rọ̀ títí dòru.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 20
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 20:7 ni o tọ