Ìṣe Àwọn Aposteli 21:26 BM

26 Ní ọjọ́ keji, Paulu mú àwọn ọkunrin náà, ó ṣe ètò láti wẹ ẹ̀jẹ́ wọn kúrò, ati tirẹ̀ pẹlu. Ó wọ Tẹmpili lọ láti lọ ṣe ìfilọ̀ ọjọ́ tí àkókò ìwẹ̀nùmọ́ wọn yóo parí, tí òun yóo mú ọrẹ ti ẹnìkọ̀ọ̀kan wọn wá.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 21

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 21:26 ni o tọ