27 Nígbà tí ọjọ́ meje náà fẹ́rẹ̀ pé, àwọn Juu láti Esia rí Paulu ninu Tẹmpili. Wọ́n bá ké ìbòòsí láàrin gbogbo èrò, wọ́n sì dọwọ́ bo Paulu,
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 21
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 21:27 ni o tọ