20 Tabi, kí àwọn tí wọ́n wà níhìn-ín fúnra wọn sọ nǹkan burúkú kan tí wọ́n rí pé mo ṣe nígbà tí mo wà níwájú ìgbìmọ̀.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 24
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 24:20 ni o tọ