Ìṣe Àwọn Aposteli 24:21 BM

21 Àfi gbolohun kan tí mo sọ nígbà tí mo dúró láàrin wọn, pé, ‘Ìdí tí a fi mú mi wá fún ìdájọ́ níwájú yín lónìí ni pé mo ní igbagbọ pé àwọn òkú yóo jinde.’ ”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 24

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 24:21 ni o tọ