Ìṣe Àwọn Aposteli 28:19 BM

19 Ṣugbọn nígbà tí àwọn Juu kò gbà pé kí wọ́n dá mi sílẹ̀, kò sí ohun tí mo tún lè ṣe jù pé kí n gbé ẹjọ́ mi wá siwaju Kesari lọ. Kì í ṣe pé mo ní ẹjọ́ kankan láti bá orílẹ̀-èdè wa rò.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 28

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 28:19 ni o tọ