20 Ìdí nìyí tí mo fi ranṣẹ pè yín láti ri yín kí n sì ba yín sọ̀rọ̀; nítorí ohun tí Israẹli ń retí ni wọ́n ṣe fi ẹ̀wọ̀n so mí báyìí.”
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 28
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 28:20 ni o tọ