Ìṣe Àwọn Aposteli 28:21 BM

21 Wọ́n dá a lóhùn pé, “A kò rí ìwé gbà nípa rẹ láti Judia; bẹ́ẹ̀ ni ẹnikẹ́ni ninu àwọn ará wa kò débí láti ròyìn rẹ tabi láti sọ̀rọ̀ rẹ ní ibi.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 28

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 28:21 ni o tọ