10 Ni òun náà bá ṣubú lulẹ̀ lẹsẹkẹsẹ níwájú Peteru, ó bá kú. Àwọn géńdé bá wọlé, wọ́n rí òkú rẹ̀. Wọ́n bá gbé e jáde, wọ́n sì sin ín sí ẹ̀bá ọkọ rẹ̀.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 5
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 5:10 ni o tọ