Ìṣe Àwọn Aposteli 5:9 BM

9 Peteru bá bi í pé, “Kí ló dé tí ẹ jọ fi ohùn ṣọ̀kan láti dán Ẹ̀mí Oluwa wò? Wo ẹsẹ̀ àwọn tí wọ́n lọ sin ọkọ rẹ lẹ́nu ọ̀nà, wọn yóo gbé ìwọ náà jáde.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 5

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 5:9 ni o tọ