Ìṣe Àwọn Aposteli 5:15 BM

15 Nígbà tí ó yá, àwọn eniyan a máa gbé àwọn aláìsàn wá sí títì lórí ẹní ati lórí ibùsùn, pé kí òjìji Peteru lè ṣíji bò wọ́n nígbà tí ó bá ń kọjá.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 5

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 5:15 ni o tọ