16 Ọpọlọpọ àwọn eniyan wá láti agbègbè ìlú Jerusalẹmu, wọ́n ń gbé àwọn aláìsàn ati àwọn tí ẹ̀mí burúkú ń dà láàmú wá; a sì mú gbogbo wọn lára dá.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 5
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 5:16 ni o tọ