Ìṣe Àwọn Aposteli 5:24 BM

24 Nígbà tí ọ̀gá àwọn ẹ̀ṣọ́ ti Tẹmpili ati àwọn olórí alufaa gbọ́ ìròyìn yìí, ọkàn wọn dàrú; wọ́n ń ronú pé, irú kí ni eléyìí?

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 5

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 5:24 ni o tọ