Ìṣe Àwọn Aposteli 5:25 BM

25 Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ẹnìkan bá dé, wọ́n sọ fún wọn pé, “Àwọn ọkunrin tí ẹ tì mọ́lé wà ninu Tẹmpili, tí wọn ń kọ́ àwọn eniyan lẹ́kọ̀ọ́.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 5

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 5:25 ni o tọ