Ìṣe Àwọn Aposteli 6:2 BM

2 Àwọn aposteli mejila bá pe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Jesu yòókù jọ, wọ́n ní, “Kò yẹ kí á fi iṣẹ́ iwaasu ọ̀rọ̀ Ọlọrun sílẹ̀, kí á máa ṣe ètò oúnjẹ.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 6

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 6:2 ni o tọ