Ìṣe Àwọn Aposteli 6:3 BM

3 Nítorí náà, ẹ̀yin ará, ẹ wá ẹni meje láàrin yín, tí wọ́n ní orúkọ rere, tí wọ́n kún fún Ẹ̀mí Mímọ́ ati ọgbọ́n, kí á yàn wọ́n láti mójútó ètò yìí.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 6

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 6:3 ni o tọ