Ìṣe Àwọn Aposteli 9:37 BM

37 Ní àkókò yìí ó wá ṣàìsàn, ó sì kú. Wọ́n bá wẹ̀ ẹ́, wọ́n tẹ́ ẹ sí yàrá lókè ní ilé pẹ̀tẹ́ẹ̀sì kan.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 9

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 9:37 ni o tọ