Ìṣe Àwọn Aposteli 9:38 BM

38 Lida kò jìnnà sí Jọpa, nítorí náà àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Jesu ní Jọpa ti gbọ́ pé Peteru wà ní Lida. Wọ́n bá rán ọkunrin meji lọ sibẹ, kí wọ́n lọ bẹ̀ ẹ́ pé kí ó má jáfara kí ó yára wá sọ́dọ̀ wọn.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 9

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 9:38 ni o tọ