Ìfihàn 14:11 BM

11 Èéfín iná oró àwọn tí wọ́n bá júbà ẹranko náà ati ère rẹ̀, tí wọ́n gba àmì orúkọ rẹ̀, yóo máa rú títí lae. Kò ní rọlẹ̀ tọ̀sán-tòru.”

Ka pipe ipin Ìfihàn 14

Wo Ìfihàn 14:11 ni o tọ