Ìfihàn 14:12 BM

12 Èyí mú kí ó di dandan fún àwọn eniyan Ọlọrun, tí wọn ń pa àṣẹ Ọlọrun mọ́, tí wọ́n sì dúró ninu igbagbọ Jesu láti ní ìfaradà.

Ka pipe ipin Ìfihàn 14

Wo Ìfihàn 14:12 ni o tọ