Ìfihàn 16:12 BM

12 Angẹli kẹfa da ohun tí ó wà ninu àwo rẹ̀ sórí odò ńlá tí wọn ń pè ní Yufurate, ni omi rẹ̀ bá gbẹ láti fi ọ̀nà sílẹ̀ fún àwọn ọba tí ń bọ̀ láti ìhà ìlà oòrùn.

Ka pipe ipin Ìfihàn 16

Wo Ìfihàn 16:12 ni o tọ