Ìfihàn 16:13 BM

13 Mo wá rí àwọn ẹ̀mí burúkú mẹta kan, wọ́n dàbí ọ̀pọ̀lọ́ ní ẹnu Ẹranko Ewèlè náà, ati ní ẹnu wolii èké náà.

Ka pipe ipin Ìfihàn 16

Wo Ìfihàn 16:13 ni o tọ