Ìfihàn 21:4 BM

4 yóo nu gbogbo omijé nù ní ojú wọn. Kò ní sí ikú mọ́, tabi ọ̀fọ̀ tabi ẹkún tabi ìrora. Nítorí àwọn ohun ti àtijọ́ ti kọjá lọ.”

Ka pipe ipin Ìfihàn 21

Wo Ìfihàn 21:4 ni o tọ