Ìfihàn 21:5 BM

5 Ẹni tí ó jókòó lórí ìtẹ́ náà sọ pé, “Mò ń sọ ohun gbogbo di titun.” Ó ní, “Kọ ọ́ sílẹ̀, nítorí òdodo ọ̀rọ̀ ati òtítọ́ ni àwọn ọ̀rọ̀ yìí.”

Ka pipe ipin Ìfihàn 21

Wo Ìfihàn 21:5 ni o tọ