Ìfihàn 4:11 BM

11 “Oluwa Ọlọrun wa, ìwọ ni ó tọ́ sí láti gba ògo, ati ọlá ati agbára.Nítorí ìwọ ni ó dá ohun gbogbo,ati pé nípa ìfẹ́ rẹ ni wọ́n ṣe wà,nípa rẹ ni a sì ṣe dá wọn.”

Ka pipe ipin Ìfihàn 4

Wo Ìfihàn 4:11 ni o tọ