Ìfihàn 5:1 BM

1 Lẹ́yìn náà, mo rí ìwé kan ní ọwọ́ ọ̀tún ẹni tí ó jókòó lórí ìtẹ́: wọ́n kọ nǹkan sí i ninu ati lóde, wọ́n sì fi èdìdì meje dì í.

Ka pipe ipin Ìfihàn 5

Wo Ìfihàn 5:1 ni o tọ