Ìfihàn 5:2 BM

2 Mo sì rí angẹli alágbára kan tí ń ké pẹlu ohùn rara pé, “Ta ni ó yẹ láti ṣí ìwé náà, ati láti tú èdìdì rẹ̀?”

Ka pipe ipin Ìfihàn 5

Wo Ìfihàn 5:2 ni o tọ