Ìfihàn 4:4 BM

4 Àwọn ìtẹ́ mẹrinlelogun ni wọ́n yí ìtẹ́ náà ká. Àwọn àgbààgbà mẹrinlelogun sì jókòó lórí ìtẹ́ mẹrinlelogun náà. Wọ́n wọ aṣọ funfun, wọ́n dé adé wúrà.

Ka pipe ipin Ìfihàn 4

Wo Ìfihàn 4:4 ni o tọ